Òwe 3:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Nítorí Jèhófà kórìíra oníbékebèke,+Ṣùgbọ́n àwọn adúróṣinṣin ni ọ̀rẹ́ Rẹ̀ tímọ́tímọ́.+ Éfésù 4:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Torí náà, ní báyìí tí ẹ ti fi ẹ̀tàn sílẹ̀, kí kálukú yín máa bá ọmọnìkejì rẹ̀ sọ òtítọ́,+ nítorí ẹ̀yà ara kan náà ni wá.+
25 Torí náà, ní báyìí tí ẹ ti fi ẹ̀tàn sílẹ̀, kí kálukú yín máa bá ọmọnìkejì rẹ̀ sọ òtítọ́,+ nítorí ẹ̀yà ara kan náà ni wá.+