Sáàmù 57:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Yóò pèsè ìrànlọ́wọ́ láti ọ̀run, yóò sì gbà mí là.+ Yóò mú kí ìsapá ẹni tó ń kù gìrì mọ́ mi já sí asán. (Sélà) Ọlọ́run yóò fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ rẹ̀ ránṣẹ́.+ Sáàmù 86:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àmọ́ ní tìrẹ, Jèhófà, o jẹ́ Ọlọ́run aláàánú, tó ń gba tẹni rò,*Tí kì í tètè bínú, tí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ àti òdodo* rẹ̀ sì pọ̀ gidigidi.+
3 Yóò pèsè ìrànlọ́wọ́ láti ọ̀run, yóò sì gbà mí là.+ Yóò mú kí ìsapá ẹni tó ń kù gìrì mọ́ mi já sí asán. (Sélà) Ọlọ́run yóò fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ rẹ̀ ránṣẹ́.+
15 Àmọ́ ní tìrẹ, Jèhófà, o jẹ́ Ọlọ́run aláàánú, tó ń gba tẹni rò,*Tí kì í tètè bínú, tí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ àti òdodo* rẹ̀ sì pọ̀ gidigidi.+