Sáàmù 40:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà, má ṣe fawọ́ àánú rẹ sẹ́yìn lórí mi. Kí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ rẹ máa dáàbò bò mí nígbà gbogbo.+ Sáàmù 61:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Yóò jókòó lórí ìtẹ́* níwájú Ọlọ́run títí láé;+Fún un ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́,* kí wọ́n lè máa dáàbò bò ó.+
11 Jèhófà, má ṣe fawọ́ àánú rẹ sẹ́yìn lórí mi. Kí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ rẹ máa dáàbò bò mí nígbà gbogbo.+
7 Yóò jókòó lórí ìtẹ́* níwájú Ọlọ́run títí láé;+Fún un ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́,* kí wọ́n lè máa dáàbò bò ó.+