-
Sáàmù 64:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Dáàbò bò mí lọ́wọ́ ohun tí àwọn ẹni ibi ń gbèrò ní ìkọ̀kọ̀,+
Lọ́wọ́ àwùjọ àwọn aṣebi.
3 Wọ́n pọ́n ahọ́n wọn bí idà;
Wọ́n dojú ọ̀rọ̀ burúkú wọn kọni bí ọfà,
-