Sáàmù 37:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, kí o sì máa rìn ní ọ̀nà rẹ̀,Yóò gbé ọ ga láti jogún ayé. Nígbà tí a bá pa àwọn ẹni burúkú rẹ́,+ wàá rí i.+
34 Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, kí o sì máa rìn ní ọ̀nà rẹ̀,Yóò gbé ọ ga láti jogún ayé. Nígbà tí a bá pa àwọn ẹni burúkú rẹ́,+ wàá rí i.+