Sáàmù 100:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ wọlé sínú àwọn ẹnubodè rẹ̀ pẹ̀lú ọpẹ́,+Sínú àwọn àgbàlá rẹ̀ pẹ̀lú ìyìn.+ Ẹ fi ọpẹ́ fún un; ẹ yin orúkọ rẹ̀.+
4 Ẹ wọlé sínú àwọn ẹnubodè rẹ̀ pẹ̀lú ọpẹ́,+Sínú àwọn àgbàlá rẹ̀ pẹ̀lú ìyìn.+ Ẹ fi ọpẹ́ fún un; ẹ yin orúkọ rẹ̀.+