Sáàmù 50:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹni tó mú ọpẹ́ wá, tí ó fi rúbọ sí mi ń yìn mí lógo,+Ní ti ẹni tó sì ń rin ọ̀nà tí ó tọ́,Màá mú kí ó rí ìgbàlà látọ̀dọ̀ mi.”+ Sáàmù 66:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Màá mú odindi ẹbọ sísun wá sí ilé rẹ;+Màá san àwọn ẹ̀jẹ́ mi fún ọ+ Sáàmù 122:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 122 Mo yọ̀ nígbà tí wọ́n sọ fún mi pé: “Jẹ́ ká lọ sí ilé Jèhófà.”+ 2 Ní báyìí, ẹsẹ̀ wa dúróNí àwọn ẹnubodè rẹ, ìwọ Jerúsálẹ́mù.+
23 Ẹni tó mú ọpẹ́ wá, tí ó fi rúbọ sí mi ń yìn mí lógo,+Ní ti ẹni tó sì ń rin ọ̀nà tí ó tọ́,Màá mú kí ó rí ìgbàlà látọ̀dọ̀ mi.”+
122 Mo yọ̀ nígbà tí wọ́n sọ fún mi pé: “Jẹ́ ká lọ sí ilé Jèhófà.”+ 2 Ní báyìí, ẹsẹ̀ wa dúróNí àwọn ẹnubodè rẹ, ìwọ Jerúsálẹ́mù.+