Sáàmù 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà Olúwa wa, orúkọ rẹ mà níyì ní gbogbo ayé o;O ti gbé ògo rẹ ga, kódà ó ga ju ọ̀run lọ!*+ Sáàmù 76:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìwọ ń tàn yanran;*O ní ọlá ńlá ju àwọn òkè tó ní àwọn ẹran.