1 Àwọn Ọba 8:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “Àmọ́, ṣé Ọlọ́run máa gbé inú ayé ni?+ Wò ó! Àwọn ọ̀run, àní, ọ̀run àwọn ọ̀run, kò lè gbà ọ́;+ ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ ti ilé tí mo kọ́ yìí!+ Sáàmù 104:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 104 Jẹ́ kí n* yin Jèhófà.+ Ìwọ Jèhófà Ọlọ́run mi, o tóbi gan-an.+ O fi ògo* àti ọlá ńlá wọ ara rẹ láṣọ.+ Sáàmù 148:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kí wọ́n máa yin orúkọ Jèhófà,Nítorí orúkọ rẹ̀ nìkan ṣoṣo ló ga kọjá ibi tó ṣeé dé.+ Iyì rẹ̀ ga ju ayé àti ọ̀run lọ.+
27 “Àmọ́, ṣé Ọlọ́run máa gbé inú ayé ni?+ Wò ó! Àwọn ọ̀run, àní, ọ̀run àwọn ọ̀run, kò lè gbà ọ́;+ ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ ti ilé tí mo kọ́ yìí!+
104 Jẹ́ kí n* yin Jèhófà.+ Ìwọ Jèhófà Ọlọ́run mi, o tóbi gan-an.+ O fi ògo* àti ọlá ńlá wọ ara rẹ láṣọ.+
13 Kí wọ́n máa yin orúkọ Jèhófà,Nítorí orúkọ rẹ̀ nìkan ṣoṣo ló ga kọjá ibi tó ṣeé dé.+ Iyì rẹ̀ ga ju ayé àti ọ̀run lọ.+