Sáàmù 86:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nítorí ẹni ńlá ni ọ́, o sì ń ṣe àwọn ohun àgbàyanu;+Ìwọ ni Ọlọ́run, ìwọ nìkan ṣoṣo.+