Diutarónómì 6:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Fetí sílẹ̀, ìwọ Ísírẹ́lì: Jèhófà Ọlọ́run wa, Jèhófà kan ṣoṣo ni.+ Sáàmù 83:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Kí àwọn èèyàn lè mọ̀ pé ìwọ, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà,+Ìwọ nìkan ṣoṣo ni Ẹni Gíga Jù Lọ lórí gbogbo ayé.+ Àìsáyà 44:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ọba Ísírẹ́lì+ àti Olùtúnrà rẹ̀,+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun: ‘Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ àti ẹni ìkẹyìn.+ Kò sí Ọlọ́run kankan àfi èmi.+ 1 Kọ́ríńtì 8:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ní báyìí, ní ti jíjẹ oúnjẹ tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà, a mọ̀ pé òrìṣà kò jẹ́ nǹkan kan+ nínú ayé àti pé kò sí Ọlọ́run míì àfi ọ̀kan ṣoṣo.+
18 Kí àwọn èèyàn lè mọ̀ pé ìwọ, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà,+Ìwọ nìkan ṣoṣo ni Ẹni Gíga Jù Lọ lórí gbogbo ayé.+
6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ọba Ísírẹ́lì+ àti Olùtúnrà rẹ̀,+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun: ‘Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ àti ẹni ìkẹyìn.+ Kò sí Ọlọ́run kankan àfi èmi.+
4 Ní báyìí, ní ti jíjẹ oúnjẹ tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà, a mọ̀ pé òrìṣà kò jẹ́ nǹkan kan+ nínú ayé àti pé kò sí Ọlọ́run míì àfi ọ̀kan ṣoṣo.+