ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 32:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  21 Wọ́n ti fi ohun tí kì í ṣe ọlọ́run+ mú mi bínú;*

      Wọ́n ti fi àwọn òrìṣà+ wọn tí kò ní láárí múnú bí mi.

      Torí náà, màá fi àwọn tí kì í ṣe èèyàn+ mú kí wọ́n jowú;

      Màá fi orílẹ̀-èdè òmùgọ̀+ mú wọn bínú.

  • 2 Àwọn Ọba 19:17, 18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Jèhófà, òótọ́ ni pé àwọn ọba Ásíríà ti pa àwọn orílẹ̀-èdè àti ilẹ̀ wọn run.+ 18 Wọ́n sì ti ju àwọn ọlọ́run wọn sínú iná, nítorí wọn kì í ṣe ọlọ́run,+ iṣẹ́ ọwọ́ èèyàn ni wọ́n,+ wọ́n jẹ́ igi àti òkúta. Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi lè pa wọ́n run.

  • Jeremáyà 16:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ǹjẹ́ èèyàn lè ṣe àwọn ọlọ́run fún ara rẹ̀

      Nígbà tí wọn kì í ṣe ọlọ́run ní ti gidi?+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́