Sáàmù 65:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 O* mú kí àwọn òkun tó ń ru gùdù rọlẹ̀+Pẹ̀lú ariwo ìgbì wọn àti rúkèrúdò àwọn orílẹ̀-èdè.+