Sáàmù 19:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Òfin Jèhófà pé,+ ó ń sọ agbára dọ̀tun.*+ Ìránnilétí Jèhófà ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé,+ ó ń sọ aláìmọ̀kan di ọlọ́gbọ́n.+ Sáàmù 119:111 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 111 Mo fi àwọn ìránnilétí rẹ ṣe ohun ìní mi tí á máa wà títí lọ,*Nítorí àwọn ni ayọ̀ ọkàn mi.+
7 Òfin Jèhófà pé,+ ó ń sọ agbára dọ̀tun.*+ Ìránnilétí Jèhófà ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé,+ ó ń sọ aláìmọ̀kan di ọlọ́gbọ́n.+