ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 10:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ìgbéraga kì í jẹ́ kí ẹni burúkú ṣe ìwádìí kankan;

      Gbogbo èrò rẹ̀ ni pé: “Kò sí Ọlọ́run.”+

  • Sáàmù 10:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ó sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: “Ọlọ́run ti gbàgbé.+

      Ó ti gbé ojú rẹ̀ kúrò.

      Kò sì ní fiyè sí i láé.”+

  • Sáàmù 73:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Nítorí mo jowú àwọn agbéraga*

      Nígbà tí mo rí àlàáfíà àwọn ẹni burúkú.+

  • Sáàmù 73:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Wọ́n ń sọ pé: “Báwo ni Ọlọ́run ṣe fẹ́ mọ̀?+

      Ṣé Ẹni Gíga Jù Lọ mọ ohun tó ń ṣẹlẹ̀ ni?”

  • Àìsáyà 29:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ó mà ṣe o, fún àwọn tó sapá gidigidi kí wọ́n lè fi ohun tí wọ́n fẹ́ ṣe* pa mọ́ fún Jèhófà.+

      Ibi tó ṣókùnkùn ni wọ́n ti ṣe iṣẹ́ wọn,

      Tí wọ́n ń sọ pé: “Ta ló rí wa,

      Ta ló mọ̀ nípa wa?”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́