Sáàmù 50:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹni tó mú ọpẹ́ wá, tí ó fi rúbọ sí mi ń yìn mí lógo,+Ní ti ẹni tó sì ń rin ọ̀nà tí ó tọ́,Màá mú kí ó rí ìgbàlà látọ̀dọ̀ mi.”+ Sáàmù 100:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ wọlé sínú àwọn ẹnubodè rẹ̀ pẹ̀lú ọpẹ́,+Sínú àwọn àgbàlá rẹ̀ pẹ̀lú ìyìn.+ Ẹ fi ọpẹ́ fún un; ẹ yin orúkọ rẹ̀.+
23 Ẹni tó mú ọpẹ́ wá, tí ó fi rúbọ sí mi ń yìn mí lógo,+Ní ti ẹni tó sì ń rin ọ̀nà tí ó tọ́,Màá mú kí ó rí ìgbàlà látọ̀dọ̀ mi.”+
4 Ẹ wọlé sínú àwọn ẹnubodè rẹ̀ pẹ̀lú ọpẹ́,+Sínú àwọn àgbàlá rẹ̀ pẹ̀lú ìyìn.+ Ẹ fi ọpẹ́ fún un; ẹ yin orúkọ rẹ̀.+