-
Émọ́sì 9:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Bí wọ́n bá fara pa mọ́ sórí òkè Kámẹ́lì,
Ibẹ̀ ni màá ti wá wọn kàn, màá sì mú wọn.+
Bí wọ́n bá sì fara pa mọ́ kúrò ní ojú mi ní ìsàlẹ̀ òkun,
Ibẹ̀ ni màá ti pàṣẹ fún ejò, á sì bù wọ́n ṣán.
-