Sáàmù 48:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Kí inú Òkè Síónì+ máa dùn,Kí àwọn ìlú* Júdà sì máa yọ̀, nítorí àwọn ìdájọ́ rẹ.+