Sáàmù 97:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Síónì gbọ́, ó sì ń yọ̀;+Inú àwọn ìlú* Júdà ń dùnNítorí àwọn ìdájọ́ rẹ, Jèhófà.+