Lúùkù 2:30, 31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 torí ojú mi ti rí ohun tí o máa fi gbani là,+ 31 èyí tí o pèsè níṣojú gbogbo èèyàn,+