Àìsáyà 52:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jèhófà ti jẹ́ kí wọ́n rí apá rẹ̀ mímọ́ lójú gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè;+Gbogbo ìkángun ayé sì máa rí bí Ọlọ́run wa ṣe ń gbani là.*+ Lúùkù 3:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 bí a ṣe kọ ọ́ sínú ìwé ọ̀rọ̀ wòlíì Àìsáyà pé: “Ohùn ẹnì kan ń ké nínú aginjù pé: ‘Ẹ ṣètò ọ̀nà Jèhófà!* Ẹ mú àwọn ọ̀nà rẹ̀ tọ́.+ Lúùkù 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 gbogbo ẹran ara* sì máa rí ìgbàlà Ọlọ́run.’”*+ Ìṣe 4:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Yàtọ̀ síyẹn, kò sí ìgbàlà lọ́dọ̀ ẹlòmíì, nítorí kò sí orúkọ míì+ lábẹ́ ọ̀run tí a fún àwọn èèyàn tí a lè tipasẹ̀ rẹ̀ rí ìgbàlà.”+
10 Jèhófà ti jẹ́ kí wọ́n rí apá rẹ̀ mímọ́ lójú gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè;+Gbogbo ìkángun ayé sì máa rí bí Ọlọ́run wa ṣe ń gbani là.*+
4 bí a ṣe kọ ọ́ sínú ìwé ọ̀rọ̀ wòlíì Àìsáyà pé: “Ohùn ẹnì kan ń ké nínú aginjù pé: ‘Ẹ ṣètò ọ̀nà Jèhófà!* Ẹ mú àwọn ọ̀nà rẹ̀ tọ́.+
12 Yàtọ̀ síyẹn, kò sí ìgbàlà lọ́dọ̀ ẹlòmíì, nítorí kò sí orúkọ míì+ lábẹ́ ọ̀run tí a fún àwọn èèyàn tí a lè tipasẹ̀ rẹ̀ rí ìgbàlà.”+