Diutarónómì 9:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Bí Jèhófà ṣe bínú sí yín gidigidi bà mí lẹ́rù gan-an,+ torí ó ṣe tán láti pa yín run. Àmọ́, Jèhófà tún fetí sí mi nígbà yẹn.+
19 Bí Jèhófà ṣe bínú sí yín gidigidi bà mí lẹ́rù gan-an,+ torí ó ṣe tán láti pa yín run. Àmọ́, Jèhófà tún fetí sí mi nígbà yẹn.+