Míkà 7:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ta ló dà bí rẹ, Ọlọ́run,Tó ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini, tó sì ń gbójú fo ìṣìnà+ àwọn tó ṣẹ́ kù nínú ogún rẹ̀?+ Kò ní máa bínú lọ títí láé,Torí inú rẹ̀ máa ń dùn sí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.+
18 Ta ló dà bí rẹ, Ọlọ́run,Tó ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini, tó sì ń gbójú fo ìṣìnà+ àwọn tó ṣẹ́ kù nínú ogún rẹ̀?+ Kò ní máa bínú lọ títí láé,Torí inú rẹ̀ máa ń dùn sí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.+