Ẹ́kísódù 15:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jáà* ni okun àti agbára mi, torí ó ti wá gbà mí là.+ Ọlọ́run mi nìyí, màá yìn ín;+ Ọlọ́run bàbá mi,+ màá gbé e ga.+
2 Jáà* ni okun àti agbára mi, torí ó ti wá gbà mí là.+ Ọlọ́run mi nìyí, màá yìn ín;+ Ọlọ́run bàbá mi,+ màá gbé e ga.+