-
Sáàmù 95:6, 7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ẹ wá, ẹ jẹ́ ká jọ́sìn, ká sì forí balẹ̀;
Ẹ jẹ́ ká kúnlẹ̀ níwájú Jèhófà Ẹni tó dá wa.+
Lónìí, tí ẹ bá fetí sí ohùn rẹ̀,+
-
Ìsíkíẹ́lì 34:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 “‘Ní tiyín, ẹ̀yin àgùntàn mi,+ ẹ̀yin àgùntàn tí mò ń bójú tó, èèyàn lẹ jẹ́, èmi sì ni Ọlọ́run yín,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”
-
-
-