1 Àwọn Ọba 9:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ní tìrẹ, tí o bá rìn níwájú mi bí Dáfídì bàbá rẹ ṣe rìn+ pẹ̀lú òtítọ́ ọkàn+ àti ìdúróṣinṣin,+ tí ò ń ṣe gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ,+ tí o sì ń pa àwọn ìlànà mi àti àwọn ìdájọ́ mi mọ́,+ Sáàmù 78:70 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 70 Ó yan Dáfídì+ ìránṣẹ́ rẹ̀,Ó sì mú un kúrò nínú ọgbà àgùntàn,+ Sáàmù 78:72 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 72 Ó fi òtítọ́ ọkàn ṣe olùṣọ́ àgùntàn wọn,+Ó sì darí wọn lọ́nà tó já fáfá.+
4 Ní tìrẹ, tí o bá rìn níwájú mi bí Dáfídì bàbá rẹ ṣe rìn+ pẹ̀lú òtítọ́ ọkàn+ àti ìdúróṣinṣin,+ tí ò ń ṣe gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ,+ tí o sì ń pa àwọn ìlànà mi àti àwọn ìdájọ́ mi mọ́,+
70 Ó yan Dáfídì+ ìránṣẹ́ rẹ̀,Ó sì mú un kúrò nínú ọgbà àgùntàn,+ Sáàmù 78:72 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 72 Ó fi òtítọ́ ọkàn ṣe olùṣọ́ àgùntàn wọn,+Ó sì darí wọn lọ́nà tó já fáfá.+