Sáàmù 27:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Má fi ojú rẹ pa mọ́ fún mi.+ Má fi ìbínú lé ìránṣẹ́ rẹ kúrò. Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi;+Má pa mí tì, má sì fi mí sílẹ̀, Ọlọ́run ìgbàlà mi. Ìdárò 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Wò ó, Jèhófà, mo wà nínú ìdààmú ńlá. Inú* mi ń dà rú. Ọkàn mi gbọgbẹ́, nítorí mo ti ya ọlọ̀tẹ̀ paraku.+ Idà ń pani ní ìta;+ ikú ń pani nínú ilé.
9 Má fi ojú rẹ pa mọ́ fún mi.+ Má fi ìbínú lé ìránṣẹ́ rẹ kúrò. Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi;+Má pa mí tì, má sì fi mí sílẹ̀, Ọlọ́run ìgbàlà mi.
20 Wò ó, Jèhófà, mo wà nínú ìdààmú ńlá. Inú* mi ń dà rú. Ọkàn mi gbọgbẹ́, nítorí mo ti ya ọlọ̀tẹ̀ paraku.+ Idà ń pani ní ìta;+ ikú ń pani nínú ilé.