ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 107:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Nítorí wọ́n ta ko ọ̀rọ̀ Ọlọ́run;

      Wọn ò ka ìmọ̀ràn Ẹni Gíga Jù Lọ sí.+

  • Àìsáyà 1:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọ̀run, sì fetí sílẹ̀, ìwọ ayé,+

      Torí Jèhófà ti sọ pé:

      “Mo ti tọ́ àwọn ọmọ,+ mo sì ti tọ́jú wọn dàgbà,

      Àmọ́ wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi.+

  • Àìsáyà 63:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àmọ́ wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i,+ wọ́n sì kó ẹ̀dùn ọkàn bá ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀.+

      Ó wá di ọ̀tá wọn,+

      Ó sì bá wọn jà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́