ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 31:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Gbogbo àwọn ọ̀tá mi ń fi mí ṣẹ̀sín,+

      Pàápàá àwọn aládùúgbò mi.

      Mo ti di ẹni àríbẹ̀rù lójú àwọn ojúlùmọ̀ mi;

      Tí wọ́n bá rí mi lóde, ṣe ni wọ́n ń sá fún mi.+

  • Sáàmù 74:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ọlọ́run, ìgbà wo ni elénìní máa pẹ̀gàn rẹ dà?+

      Ṣé ọ̀tá yóò máa hùwà àìlọ́wọ̀ sí orúkọ rẹ títí láé ni?+

  • Sáàmù 79:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 A ti di ẹni ẹ̀gàn lójú àwọn aládùúgbò wa;+

      Àwọn tó yí wa ká ń fi wá ṣẹ̀sín, wọ́n sì ń fi wá ṣe yẹ̀yẹ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́