Àìsáyà 49:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ṣé obìnrin lè gbàgbé ọmọ rẹ̀ tó ṣì ń mu ọmúTàbí kó má ṣàánú ọmọ tó lóyún rẹ̀? Tí àwọn obìnrin yìí bá tiẹ̀ gbàgbé, mi ò jẹ́ gbàgbé rẹ láé.+
15 Ṣé obìnrin lè gbàgbé ọmọ rẹ̀ tó ṣì ń mu ọmúTàbí kó má ṣàánú ọmọ tó lóyún rẹ̀? Tí àwọn obìnrin yìí bá tiẹ̀ gbàgbé, mi ò jẹ́ gbàgbé rẹ láé.+