Àìsáyà 44:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “Rántí àwọn nǹkan yìí, ìwọ Jékọ́bù àti ìwọ Ísírẹ́lì,Torí pé ìránṣẹ́ mi ni ọ́. Èmi ni mo dá ọ, ìránṣẹ́ mi sì ni ọ́.+ Ìwọ Ísírẹ́lì, mi ò ní gbàgbé rẹ.+ Jeremáyà 31:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Ǹjẹ́ Éfúrémù kì í ṣe ọmọ mi àtàtà, ọmọ tí mo nífẹ̀ẹ́?+ Torí bí mo ṣe ń sọ̀rọ̀ sí i tó, síbẹ̀ mo ṣì ń rántí rẹ̀. Ìdí nìyẹn tí ọkàn* mi fi gbé sókè nítorí rẹ̀.+ Ó sì dájú pé màá ṣàánú rẹ̀,” ni Jèhófà wí.+
21 “Rántí àwọn nǹkan yìí, ìwọ Jékọ́bù àti ìwọ Ísírẹ́lì,Torí pé ìránṣẹ́ mi ni ọ́. Èmi ni mo dá ọ, ìránṣẹ́ mi sì ni ọ́.+ Ìwọ Ísírẹ́lì, mi ò ní gbàgbé rẹ.+
20 “Ǹjẹ́ Éfúrémù kì í ṣe ọmọ mi àtàtà, ọmọ tí mo nífẹ̀ẹ́?+ Torí bí mo ṣe ń sọ̀rọ̀ sí i tó, síbẹ̀ mo ṣì ń rántí rẹ̀. Ìdí nìyẹn tí ọkàn* mi fi gbé sókè nítorí rẹ̀.+ Ó sì dájú pé màá ṣàánú rẹ̀,” ni Jèhófà wí.+