Àìsáyà 60:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn àjèjì máa mọ àwọn ògiri rẹ,Àwọn ọba wọn sì máa ṣe ìránṣẹ́ fún ọ,+Torí ìbínú ni mo fi kọ lù ọ́,Àmọ́ màá fi ojúure* mi ṣàánú rẹ.+
10 Àwọn àjèjì máa mọ àwọn ògiri rẹ,Àwọn ọba wọn sì máa ṣe ìránṣẹ́ fún ọ,+Torí ìbínú ni mo fi kọ lù ọ́,Àmọ́ màá fi ojúure* mi ṣàánú rẹ.+