ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sírà 7:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Ìyìn ni fún Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wa, ẹni tó fi sí ọba lọ́kàn láti ṣe ilé Jèhófà tó wà ní Jerúsálẹ́mù lọ́ṣọ̀ọ́!+

  • Nehemáyà 2:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Lẹ́yìn náà, mo sọ fún ọba pé: “Tó bá dáa lójú ọba, jẹ́ kí wọ́n fún mi ní àwọn lẹ́tà tí màá fún àwọn gómìnà agbègbè tó wà ní Ìkọjá Odò,*+ kí wọ́n lè jẹ́ kí n kọjá títí màá fi dé Júdà 8 àti lẹ́tà tí màá fún Ásáfù tó ń ṣọ́ Ọgbà Ọba,* kó lè fún mi ní gẹdú tí màá fi ṣe òpó àwọn ẹnubodè Odi+ Ilé Ọlọ́run* àti ògiri ìlú náà+ pẹ̀lú ilé tí màá gbé.” Nítorí náà, ọba kó wọn fún mi,+ torí pé ọwọ́ rere Ọlọ́run mi wà lára mi.+

  • Àìsáyà 49:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Àwọn ọba máa di olùtọ́jú rẹ,+

      Àwọn ọmọ wọn obìnrin sì máa di alágbàtọ́ rẹ.

      Wọ́n máa tẹrí ba fún ọ, wọ́n á sì dojú bolẹ̀,+

      Wọ́n máa lá iyẹ̀pẹ̀ ẹsẹ̀ rẹ,+

      Wàá sì mọ̀ pé èmi ni Jèhófà;

      Ojú ò ní ti àwọn tó bá gbẹ́kẹ̀ lé mi.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́