Sáàmù 147:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà ń kọ́ Jerúsálẹ́mù;+Ó ń kó àwọn tí wọ́n fọ́n ká lára Ísírẹ́lì jọ.+ Jeremáyà 33:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Màá mú àwọn ará Júdà àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó wà lóko ẹrú pa dà,+ màá sì fún wọn lókun bí mo ti ṣe ní ìbẹ̀rẹ̀.+
7 Màá mú àwọn ará Júdà àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó wà lóko ẹrú pa dà,+ màá sì fún wọn lókun bí mo ti ṣe ní ìbẹ̀rẹ̀.+