Sáàmù 102:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jèhófà máa tún Síónì kọ́;+Á fara hàn nínú ògo rẹ̀.+