Àìsáyà 60:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 60 “Dìde, ìwọ obìnrin,+ tan ìmọ́lẹ̀, torí ìmọ́lẹ̀ rẹ ti dé. Ògo Jèhófà ń tàn sára rẹ.+