Ẹ́kísódù 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà sì sọ pé: “Mo ti rí ìyà tó ń jẹ àwọn èèyàn mi ní Íjíbítì, mo sì ti gbọ́ igbe wọn torí àwọn tó ń fipá kó wọn ṣiṣẹ́; mo mọ̀ dáadáa pé wọ́n ń jẹ̀rora.+ Àìsáyà 61:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 61 Ẹ̀mí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára mi,+Torí Jèhófà ti yàn mí kí n lè kéde ìhìn rere fún àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Ó rán mi láti di ọgbẹ́ àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn,Láti kéde òmìnira fún àwọn ẹrú,Pé ojú àwọn ẹlẹ́wọ̀n sì máa là rekete,+
7 Jèhófà sì sọ pé: “Mo ti rí ìyà tó ń jẹ àwọn èèyàn mi ní Íjíbítì, mo sì ti gbọ́ igbe wọn torí àwọn tó ń fipá kó wọn ṣiṣẹ́; mo mọ̀ dáadáa pé wọ́n ń jẹ̀rora.+
61 Ẹ̀mí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára mi,+Torí Jèhófà ti yàn mí kí n lè kéde ìhìn rere fún àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Ó rán mi láti di ọgbẹ́ àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn,Láti kéde òmìnira fún àwọn ẹrú,Pé ojú àwọn ẹlẹ́wọ̀n sì máa là rekete,+