Àìsáyà 11:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ní ọjọ́ yẹn, gbòǹgbò Jésè+ máa dúró bí àmì* fún àwọn èèyàn.+ Ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn orílẹ̀-èdè máa yíjú sí fún ìtọ́sọ́nà,*+Ibi ìsinmi rẹ̀ sì máa di ológo. Àìsáyà 49:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Wò ó! Màá gbé ọwọ́ mi sókè sí àwọn orílẹ̀-èdè,Màá sì gbé àmì* mi sókè sí àwọn èèyàn.+ Wọ́n máa fi ọwọ́ wọn gbé àwọn ọmọkùnrin rẹ wá,*Wọ́n sì máa gbé àwọn ọmọbìnrin rẹ sí èjìká wọn.+ Àìsáyà 60:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn orílẹ̀-èdè máa lọ sínú ìmọ́lẹ̀ rẹ,+Àwọn ọba+ sì máa lọ sínú ẹwà rẹ tó ń tàn.*+
10 Ní ọjọ́ yẹn, gbòǹgbò Jésè+ máa dúró bí àmì* fún àwọn èèyàn.+ Ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn orílẹ̀-èdè máa yíjú sí fún ìtọ́sọ́nà,*+Ibi ìsinmi rẹ̀ sì máa di ológo.
22 Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Wò ó! Màá gbé ọwọ́ mi sókè sí àwọn orílẹ̀-èdè,Màá sì gbé àmì* mi sókè sí àwọn èèyàn.+ Wọ́n máa fi ọwọ́ wọn gbé àwọn ọmọkùnrin rẹ wá,*Wọ́n sì máa gbé àwọn ọmọbìnrin rẹ sí èjìká wọn.+