Àìsáyà 66:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Bí ọ̀run tuntun àti ayé tuntun+ tí mò ń dá ṣe máa dúró níwájú mi,” ni Jèhófà wí, “bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ* yín àti orúkọ yín ṣe máa dúró.”+
22 “Bí ọ̀run tuntun àti ayé tuntun+ tí mò ń dá ṣe máa dúró níwájú mi,” ni Jèhófà wí, “bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ* yín àti orúkọ yín ṣe máa dúró.”+