Sáàmù 12:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Nítorí ìnira àwọn tí ìyà ń jẹ,Nítorí ìkérora àwọn aláìní,+Màá dìde láti gbé ìgbésẹ̀,” ni Jèhófà wí. “Màá gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn tó kórìíra wọn.”* Òwe 22:22, 23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Má ja tálákà lólè torí pé kò ní lọ́wọ́,+Má sì fojú aláìní gbolẹ̀ ní ẹnubodè,+23 Nítorí Jèhófà fúnra rẹ̀ yóò gba ẹjọ́ wọn rò+Yóò sì gba ẹ̀mí* àwọn tó lù wọ́n ní jìbìtì. Jémíìsì 5:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Wò ó! Owó iṣẹ́ tí ẹ ò san fún àwọn òṣìṣẹ́ tó kórè oko yín ń ké jáde ṣáá, igbe tí àwọn olùkórè ń ké fún ìrànwọ́ sì ti dé etí Jèhófà* Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+
5 “Nítorí ìnira àwọn tí ìyà ń jẹ,Nítorí ìkérora àwọn aláìní,+Màá dìde láti gbé ìgbésẹ̀,” ni Jèhófà wí. “Màá gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn tó kórìíra wọn.”*
22 Má ja tálákà lólè torí pé kò ní lọ́wọ́,+Má sì fojú aláìní gbolẹ̀ ní ẹnubodè,+23 Nítorí Jèhófà fúnra rẹ̀ yóò gba ẹjọ́ wọn rò+Yóò sì gba ẹ̀mí* àwọn tó lù wọ́n ní jìbìtì.
4 Wò ó! Owó iṣẹ́ tí ẹ ò san fún àwọn òṣìṣẹ́ tó kórè oko yín ń ké jáde ṣáá, igbe tí àwọn olùkórè ń ké fún ìrànwọ́ sì ti dé etí Jèhófà* Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+