Ẹ́sírà 9:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Lẹ́yìn gbogbo ohun tó dé bá wa nítorí ìwà burúkú wa àti ẹ̀ṣẹ̀ ńlá tí a dá, ìwọ Ọlọ́run wa kò fi ìyà tó tọ́ sí wa jẹ wá nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa,+ o sì ti jẹ́ kí àwa tí a wà níbí sá àsálà,+ Sáàmù 130:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Jáà,* tó bá jẹ́ pé àṣìṣe lò ń wò,*Jèhófà, ta ló lè dúró?+ Àìsáyà 55:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kí èèyàn burúkú fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀,+Kí ẹni ibi sì yí èrò rẹ̀ pa dà;Kó pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ẹni tó máa ṣàánú rẹ̀,+Sọ́dọ̀ Ọlọ́run wa, torí ó máa dárí jini fàlàlà.*+
13 Lẹ́yìn gbogbo ohun tó dé bá wa nítorí ìwà burúkú wa àti ẹ̀ṣẹ̀ ńlá tí a dá, ìwọ Ọlọ́run wa kò fi ìyà tó tọ́ sí wa jẹ wá nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa,+ o sì ti jẹ́ kí àwa tí a wà níbí sá àsálà,+
7 Kí èèyàn burúkú fi ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀,+Kí ẹni ibi sì yí èrò rẹ̀ pa dà;Kó pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ẹni tó máa ṣàánú rẹ̀,+Sọ́dọ̀ Ọlọ́run wa, torí ó máa dárí jini fàlàlà.*+