Sáàmù 21:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 O sọ ọ́ di ẹni ìbùkún títí láé;+O mú kí ó máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀ nítorí o* wà pẹ̀lú rẹ̀.+ Mátíù 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Aláyọ̀ ni àwọn tí ọkàn wọn mọ́,+ torí wọ́n máa rí Ọlọ́run.