Sáàmù 16:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 O jẹ́ kí n mọ ọ̀nà ìyè.+ Ayọ̀ púpọ̀+ wà ní iwájú* rẹ,Ìdùnnú* sì wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ títí láé. Sáàmù 45:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 O nífẹ̀ẹ́ òdodo,+ o sì kórìíra ìwà burúkú.+ Ìdí nìyẹn tí Ọlọ́run, àní Ọlọ́run rẹ, fi fòróró ayọ̀+ yàn ọ́+ ju àwọn ojúgbà rẹ.
7 O nífẹ̀ẹ́ òdodo,+ o sì kórìíra ìwà burúkú.+ Ìdí nìyẹn tí Ọlọ́run, àní Ọlọ́run rẹ, fi fòróró ayọ̀+ yàn ọ́+ ju àwọn ojúgbà rẹ.