Sáàmù 21:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 O sọ ọ́ di ẹni ìbùkún títí láé;+O mú kí ó máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀ nítorí o* wà pẹ̀lú rẹ̀.+