Jémíìsì 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Gbogbo ẹ̀bùn rere àti gbogbo ọrẹ pípé wá láti òkè,+ ó ń wá látọ̀dọ̀ Baba àwọn ìmọ́lẹ̀ àtọ̀runwá,+ ẹni tí kì í yí pa dà, tí kì í sì í sún kiri bí òjìji.*+ 1 Jòhánù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ohun tí a gbọ́ látọ̀dọ̀ rẹ̀, tí a sì ń sọ fún yín ni pé: Ọlọ́run jẹ́ ìmọ́lẹ̀,+ kò sì sí òkùnkùn kankan nínú rẹ̀* rárá.
17 Gbogbo ẹ̀bùn rere àti gbogbo ọrẹ pípé wá láti òkè,+ ó ń wá látọ̀dọ̀ Baba àwọn ìmọ́lẹ̀ àtọ̀runwá,+ ẹni tí kì í yí pa dà, tí kì í sì í sún kiri bí òjìji.*+
5 Ohun tí a gbọ́ látọ̀dọ̀ rẹ̀, tí a sì ń sọ fún yín ni pé: Ọlọ́run jẹ́ ìmọ́lẹ̀,+ kò sì sí òkùnkùn kankan nínú rẹ̀* rárá.