Àìsáyà 40:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ẹnì kan wà tó ń gbé orí òbìrìkìtì* ayé,+Àwọn tó ń gbé inú rẹ̀ sì dà bíi tata,Ó ń na ọ̀run bí aṣọ fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ tó ní ihò wínníwínní,Ó sì tẹ́ ẹ bí àgọ́ láti máa gbé.+
22 Ẹnì kan wà tó ń gbé orí òbìrìkìtì* ayé,+Àwọn tó ń gbé inú rẹ̀ sì dà bíi tata,Ó ń na ọ̀run bí aṣọ fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ tó ní ihò wínníwínní,Ó sì tẹ́ ẹ bí àgọ́ láti máa gbé.+