Sáàmù 18:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ó wá fi òkùnkùn bo ara rẹ̀,+Ó bò ó yí ká bí àgọ́,Nínú ojú ọ̀run tó ṣú dẹ̀dẹ̀.+ Émọ́sì 9:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 ‘Ẹni tó ṣe àwọn àtẹ̀gùn Rẹ̀ lọ sí ọ̀run,Tó sì dá àwọn nǹkan sí òkè ayé;Ẹni tó ń wọ́ omi jọ látinú òkun,Kí ó lè dà á sórí ilẹ̀,+Jèhófà ni orúkọ rẹ̀.’+
6 ‘Ẹni tó ṣe àwọn àtẹ̀gùn Rẹ̀ lọ sí ọ̀run,Tó sì dá àwọn nǹkan sí òkè ayé;Ẹni tó ń wọ́ omi jọ látinú òkun,Kí ó lè dà á sórí ilẹ̀,+Jèhófà ni orúkọ rẹ̀.’+