Jóòbù 36:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ó ń fa àwọn ẹ̀kán omi sókè;+Omi inú àwọsánmà* rẹ̀ ń di òjò;28 Àwọsánmà* wá rọ òjò;+Ó rọ̀ sórí aráyé. Sáàmù 135:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó ń mú kí ìkùukùu* ròkè láti ìkángun ayé;Ó ń ṣe mànàmáná* fún òjò;Ó ń mú ẹ̀fúùfù jáde látinú àwọn ilé ìṣúra rẹ̀.+
27 Ó ń fa àwọn ẹ̀kán omi sókè;+Omi inú àwọsánmà* rẹ̀ ń di òjò;28 Àwọsánmà* wá rọ òjò;+Ó rọ̀ sórí aráyé.
7 Ó ń mú kí ìkùukùu* ròkè láti ìkángun ayé;Ó ń ṣe mànàmáná* fún òjò;Ó ń mú ẹ̀fúùfù jáde látinú àwọn ilé ìṣúra rẹ̀.+