-
Ìsíkíẹ́lì 1:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Àwọn ẹ̀dá alààyè náà rí bí ẹyin iná tó ń jó, ohun kan tó rí bí ògùṣọ̀ tí iná rẹ̀ mọ́lẹ̀ yòò ń lọ síwá-sẹ́yìn láàárín àwọn ẹ̀dá alààyè náà, mànàmáná sì ń kọ látinú iná náà.+
-