Sáàmù 91:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí ó máa pàṣẹ fún àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ nítorí rẹ,+Láti máa ṣọ́ ọ ní gbogbo ọ̀nà rẹ.+ Lúùkù 22:43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Áńgẹ́lì kan wá fara hàn án láti ọ̀run, ó sì fún un lókun.+